Oriki Orixá Ogun
Oriki Ogun 1 Ògún pèlé o ! Ògún alákáyé, Osìn ímolè. Ògún alada méjì. O fi òkan sán oko. O fi òkan ye ona. Ojó Ògún ntòkè bò. Aso iná ló mu bora, Ewu ejè lówò. Ògún edun olú irin. Awònye òrìsà tií bura re sán wònyìnwònyìn. Ògún onire alagbara. A mu wodò, Ògún si …