Oriki Orisa Elegbara Exu….Laroye

Oriki Orisa Elegbara Exu….Laroye

 

Èsù òta òrìsà.

Osétùrá ni oruko bàbá mò ó.

Alágogo Ìjà ni orúko ìyá npè é,

Èsù Òdàrà, omokùnrin Ìdólófin,

O lé sónsó sí orí esè elésè

Kò je, kò jé kí eni nje gbé mì,

A kìì lówó láì mú ti Èsù kúrò,

A kìì lóyò láì mú ti Èsù kúrò,

Asòntún se òsì láì ní ítijú,

Èsù àpáta sómo olómo lénu,

O fi okúta dípò iyò.

Lóògemo òrun, a nla kálù,

Pàápa-wàrá, a túká máse sà,

Èsù máse mí, omo elòmíràn ni o se.

Èsù òta òrìsà.

Osétùrá ni oruko bàbá mò ó.

Alágogo Ìjà ni orúko ìyá npè é,

Èsù Òdàrà, omokùnrin Ìdólófin,

O lé sónsó sí orí esè elésè

Kò je, kò jé kí eni nje gbé mì,

A kìì lówó láì mú ti Èsù kúrò,

A kìì lóyò láì mú ti Èsù kúrò,

Asòntún se òsì láì ní ítijú,

Èsù àpáta sómo olómo lénu,

O fi okúta dípò iyò.

Lóògemo òrun, a nla kálù,

Pàápa-wàrá, a túká máse sà,

Èsù máse mí, omo elòmíràn ni o se.

Quer ler mais Orikis: https://ileaxeifaorixa.com.br/orikis-rezas

Deixe um comentário

O seu endereço de e-mail não será publicado. Campos obrigatórios são marcados com *

Rolar para cima